Ọ̀tún wẹ òsì, òsì wẹ ọ̀tun, lọwọ́ fi ńmọ́.
#Translation:
The right hand washing the left hand and the left hand washing the right hand make both hands clean.
#Wisdom:
[Reciprocate acts of kindness: we all win when everyone gives; everyone has something to give others.]
Iranlọwọ Ọlọrun kòní jina si ẹnikànkàn wa laṣẹ Èdumare.
A kú ojumọ.
Comments
Post a Comment